1 Kíróníkà 1:21-26 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

21. Hádórámì, Úsálì, àti Díkílà

22. Ébálì, Ábímáélì, Ṣébà.

23. Ófírì, Háfílà, àti Jóbábù. Gbogbo àwọn wọ̀nyí sì jẹ́ àwọn ọmọ Jókítanì.

24. Ṣémù, Árífákásádì, Sẹ́bà,

25. Ébérì, Pélégì. Réù,

26. Ṣérúgì, Náhórì, Térà:

1 Kíróníkà 1