1 Kíróníkà 1:17-22 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

17. Àwọn ọmọ Ṣémù:Élámù. Ásúrì, Árífákásádì, Lúdì àti Árámù.Àwọn ará Árámù:Usì Húlì, Gétérì, àti Méṣékì.

18. Árífákásádì sì jẹ́ Baba Ṣélà,àti Ṣélà sì jẹ́ Baba Ébérì.

19. A bí àwọn ọmọ méjì fún Ébérì:Orúkọ ọ̀kan ni Pélégì, nítorí ní àkókò tirẹ̀ a pín ayé; orúkọ ẹ̀gbọ́n Rẹ̀ ọkùnrin a sì máa jẹ́ Jókítanì.

20. Jókítanì sì jẹ́ Baba fúnHímódádì, Ṣéléfì, Hásárímáfétì, Jérà.

21. Hádórámì, Úsálì, àti Díkílà

22. Ébálì, Ábímáélì, Ṣébà.

1 Kíróníkà 1