1 Kíróníkà 1:14-19 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

14. Àwọn ará Jébúsì, àwọn ará Ámórì, àwọn ará Gírígásì

15. Àwọn Hífì, àwọn ará Áríkì, àwọn ará Hamati-Ṣínì,

16. Àwọn ará Árífádù, àwọn ará, Ṣémárì, àwọn ará Hámátì.

17. Àwọn ọmọ Ṣémù:Élámù. Ásúrì, Árífákásádì, Lúdì àti Árámù.Àwọn ará Árámù:Usì Húlì, Gétérì, àti Méṣékì.

18. Árífákásádì sì jẹ́ Baba Ṣélà,àti Ṣélà sì jẹ́ Baba Ébérì.

19. A bí àwọn ọmọ méjì fún Ébérì:Orúkọ ọ̀kan ni Pélégì, nítorí ní àkókò tirẹ̀ a pín ayé; orúkọ ẹ̀gbọ́n Rẹ̀ ọkùnrin a sì máa jẹ́ Jókítanì.

1 Kíróníkà 1